Ẹkisodu 10:28 BM

28 Farao bá lé Mose, ó ní, “Kúrò lọ́dọ̀ mi; kí o sì ṣọ́ra rẹ gidigidi, n kò gbọdọ̀ tún rí ọ níwájú mi mọ́; ní ọjọ́ tí mo bá tún fi ojú kàn ọ́, ọjọ́ náà ni o óo kú!”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 10

Wo Ẹkisodu 10:28 ni o tọ