Ẹkisodu 11:10 BM

10 Mose ati Aaroni ṣe gbogbo iṣẹ́ ìyanu tí wọn ṣe níwájú Farao, ṣugbọn OLUWA sì mú kí ọkàn Farao le, kò sì jẹ́ kí àwọn eniyan Israẹli lọ kúrò ní ilẹ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 11

Wo Ẹkisodu 11:10 ni o tọ