Ẹkisodu 12:25 BM

25 Nígbà tí ẹ bá sì dé ilẹ̀ tí OLUWA yóo fún yín gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe ìlérí, ẹ gbọdọ̀ máa ṣe ìsìn yìí.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 12

Wo Ẹkisodu 12:25 ni o tọ