Ẹkisodu 12:46 BM

46 Ilé tí ẹ bá ti se oúnjẹ yìí ni ẹ ti gbọdọ̀ jẹ gbogbo rẹ̀, ẹ kò gbọdọ̀ mú ninu ẹran rẹ̀ jáde, ẹ kò sì gbọdọ̀ fọ́ egungun rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 12

Wo Ẹkisodu 12:46 ni o tọ