Ẹkisodu 12:6 BM

6 Wọ́n óo so ẹran wọn mọ́lẹ̀ títí di ọjọ́ kẹrinla oṣù yìí. Nígbà tí ó bá di ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ náà, gbogbo ìjọ eniyan Israẹli yóo pa ẹran wọn.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 12

Wo Ẹkisodu 12:6 ni o tọ