Ẹkisodu 12:9 BM

9 Ẹ kò gbọdọ̀ jẹ ninu ẹran yìí ní tútù, tabi bíbọ̀; sísun ni kí ẹ sun ún; ati orí rẹ̀ ati ẹsẹ̀ rẹ̀, ati àwọn nǹkan inú rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 12

Wo Ẹkisodu 12:9 ni o tọ