Ẹkisodu 13:16 BM

16 Ẹ fi ṣe àmì sí ọwọ́ yín, ati ìgbàjú sí iwájú yín, nítorí pé pẹlu ipá ni OLUWA fi mú wa jáde ní ilẹ̀ Ijipti.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 13

Wo Ẹkisodu 13:16 ni o tọ