Ẹkisodu 13:6 BM

6 Ọjọ́ meje ni ẹ óo fi jẹ burẹdi tí kò ní ìwúkàrà, ní ọjọ́ keje ẹ óo pe àpèjọ kan fún OLUWA láti ṣe àjọ̀dún.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 13

Wo Ẹkisodu 13:6 ni o tọ