Ẹkisodu 14:20 BM

20 Ọ̀wọ̀n ìkùukùu náà sì wà láàrin àwọn ọmọ ogun Ijipti ati àwọn ọmọ ogun Israẹli, ìkùukùu náà ṣókùnkùn dudu títí tí gbogbo òru ọjọ́ náà fi kọjá, wọn kò sì súnmọ́ ara wọn.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 14

Wo Ẹkisodu 14:20 ni o tọ