Ẹkisodu 14:29 BM

29 Ṣugbọn àwọn ọmọ Israẹli rìn kọjá lórí ìyàngbẹ ilẹ̀ ninu Òkun Pupa, omi rẹ̀ sì dàbí ògiri ní ẹ̀gbẹ́ ọ̀tún ati ní ẹ̀gbẹ́ òsì wọn.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 14

Wo Ẹkisodu 14:29 ni o tọ