Ẹkisodu 14:31 BM

31 Àwọn ọmọ Israẹli rí ohun ńlá tí OLUWA ṣe sí àwọn ará Ijipti, wọ́n bẹ̀rù OLUWA, wọ́n sì gba OLUWA gbọ́, ati Mose, iranṣẹ rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 14

Wo Ẹkisodu 14:31 ni o tọ