Ẹkisodu 14:8 BM

8 OLUWA mú ọkàn Farao, ọba Ijipti le, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí lépa àwọn ọmọ Israẹli bí wọ́n ti ń lọ tìgboyà-tìgboyà.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 14

Wo Ẹkisodu 14:8 ni o tọ