Ẹkisodu 15:13 BM

13 O ti fi ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ṣe amọ̀nà àwọn eniyan rẹ tí o rà pada,o ti fi agbára rẹ tọ́ wọn lọ sí ibùgbé mímọ́ rẹ.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 15

Wo Ẹkisodu 15:13 ni o tọ