2 OLUWA ni agbára ati orin mi,ó ti gbà mí là, òun ni Ọlọrun mi,n óo máa yìn ín.Òun ni Ọlọrun àwọn baba ńlá mi;n óo máa gbé e ga.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 15
Wo Ẹkisodu 15:2 ni o tọ