Ẹkisodu 15:7 BM

7 Ninu títóbi ọláńlá rẹ, o dojú àwọn ọ̀tá rẹ bolẹ̀,o fa ibinu yọ, ó sì jó wọn bí àgékù koríko.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 15

Wo Ẹkisodu 15:7 ni o tọ