Ẹkisodu 15:9 BM

9 Ọ̀tá wí pé,‘N óo lé wọn, ọwọ́ mi yóo sì tẹ̀ wọ́n;n óo pín ìkógun,n óo sì tẹ́ ìfẹ́ ọkàn mi lọ́rùn lára wọn.N óo fa idà mi yọ,ọwọ́ mi ni n óo sì fi pa wọ́n run.’

Ka pipe ipin Ẹkisodu 15

Wo Ẹkisodu 15:9 ni o tọ