Ẹkisodu 16:13 BM

13 Nígbà tí ó di ìrọ̀lẹ́, àwọn ẹyẹ àparò fò dé, wọ́n sì bo gbogbo àgọ́ náà; nígbà tí ilẹ̀ ọjọ́ keji mọ́, ìrì sẹ̀ bo gbogbo àgọ́ náà.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 16

Wo Ẹkisodu 16:13 ni o tọ