21 Ní àràárọ̀ ni olukuluku máa ń kó ohun tí ó bá lè jẹ tán, nígbà tí oòrùn bá gòkè, gbogbo èyí tí ó bá wà nílẹ̀ yóo sì yọ́ dànù.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 16
Wo Ẹkisodu 16:21 ni o tọ