Ẹkisodu 16:24 BM

24 Wọ́n bá fi ìyókù pamọ́ títí di òwúrọ̀ gẹ́gẹ́ bí Mose ti sọ fún wọn; kò sì rùn, bẹ́ẹ̀ ni kò yọ ìdin.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 16

Wo Ẹkisodu 16:24 ni o tọ