Ẹkisodu 16:31 BM

31 Àwọn eniyan Israẹli pe orúkọ oúnjẹ náà ní mana, ó rí rínbíntín-rínbíntín, ó dàbí èso igi korianda, ó funfun, ó sì dùn lẹ́nu bíi burẹdi fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ tí wọ́n fi oyin ṣe.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 16

Wo Ẹkisodu 16:31 ni o tọ