Ẹkisodu 16:7 BM

7 Nígbà tí ó bá di òwúrọ̀ ọ̀la, ẹ óo rí ògo OLUWA, nítorí ó ti gbọ́ kíkùn tí ẹ̀ ń kùn sí i. Kí ni àwa yìí jẹ́, tí ẹ óo fi máa kùn sí wa?”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 16

Wo Ẹkisodu 16:7 ni o tọ