Ẹkisodu 17:4 BM

4 Mose bá tún kígbe pe OLUWA, ó ní, “Kí ni n óo ṣe sí àwọn eniyan wọnyi, wọ́n ti múra láti sọ mí lókùúta.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 17

Wo Ẹkisodu 17:4 ni o tọ