Ẹkisodu 17:9 BM

9 Mose bá wí fún Joṣua pé, “Yan àwọn akọni ọkunrin láàrin yín kí o sì jáde lọ láti bá àwọn ará Amaleki jagun lọ́la, n óo dúró ní orí òkè pẹlu ọ̀pá Ọlọrun ní ọwọ́ mi.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 17

Wo Ẹkisodu 17:9 ni o tọ