Ẹkisodu 18:16 BM

16 Nígbà tí èdè-àìyedè bá wà láàrin àwọn aládùúgbò meji, èmi ni mo máa ń parí rẹ̀ fún wọn. Èmi náà ni mo sì máa ń sọ òfin Ọlọrun, ati àwọn ìpinnu rẹ̀ fún wọn.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 18

Wo Ẹkisodu 18:16 ni o tọ