Ẹkisodu 18:20 BM

20 ó sì dára bákan náà pẹlu kí o máa kọ́ wọn ní òfin ati ìlànà, kí o sì máa fi ọ̀nà tí wọn yóo tọ̀ hàn wọ́n, ati ohun tí wọ́n gbọdọ̀ máa ṣe.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 18

Wo Ẹkisodu 18:20 ni o tọ