Ẹkisodu 18:26 BM

26 Wọ́n ń ṣe ìdájọ́ àwọn eniyan náà nígbà gbogbo; àwọn ọ̀rọ̀ tí ó bá fẹ́ díjú nìkan ni wọ́n ń kó tọ Mose lọ, wọ́n ń yanjú àwọn ọ̀rọ̀ kéékèèké láàrin ara wọn.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 18

Wo Ẹkisodu 18:26 ni o tọ