5 Jẹtiro, baba iyawo Mose, mú iyawo Mose, ati àwọn ọmọ rẹ̀ mejeeji tọ̀ ọ́ wá ní aṣálẹ̀, níbi tí wọ́n pàgọ́ sí níbi òkè Ọlọrun.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 18
Wo Ẹkisodu 18:5 ni o tọ