Ẹkisodu 18:7 BM

7 Mose lọ pàdé wọn, ó wólẹ̀ níwájú Jẹtiro, ó fi ẹnu kò ó lẹ́nu, wọ́n bèèrè alaafia ara wọn, wọ́n sì wọ inú àgọ́ lọ.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 18

Wo Ẹkisodu 18:7 ni o tọ