11 nítorí pé ní ọjọ́ kẹta yìí ni èmi OLUWA óo sọ̀kalẹ̀ sórí òkè Sinai, lójú gbogbo wọn.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 19
Wo Ẹkisodu 19:11 ni o tọ