15 Ó sọ fún wọn pé, “Ẹ múrasílẹ̀ di ọ̀tunla, ẹ má ṣe súnmọ́ obinrin láti bá a lòpọ̀.”
Ka pipe ipin Ẹkisodu 19
Wo Ẹkisodu 19:15 ni o tọ