5 Nítorí náà, bí ẹ bá gbọ́ tèmi, tí ẹ sì pa majẹmu mi mọ́ ẹ óo jẹ́ tèmi láàrin gbogbo eniyan, nítorí pé tèmi ni gbogbo ayé yìí patapata;
Ka pipe ipin Ẹkisodu 19
Wo Ẹkisodu 19:5 ni o tọ