Ẹkisodu 2:15 BM

15 Nígbà tí Farao gbọ́, ó ń wá ọ̀nà àtipa Mose.Ṣugbọn Mose sálọ mọ́ ọn lọ́wọ́, ó lọ sí ilẹ̀ Midiani, ó sì jókòó lẹ́bàá kànga kan.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 2

Wo Ẹkisodu 2:15 ni o tọ