19 Wọ́n dá a lóhùn pé, “Ará Ijipti kan ni ó gbà wá kalẹ̀ lọ́wọ́ àwọn olùṣọ́-aguntan náà, ó tilẹ̀ tún bá wa pọn omi fún agbo ẹran wa.”
Ka pipe ipin Ẹkisodu 2
Wo Ẹkisodu 2:19 ni o tọ