Ẹkisodu 2:2 BM

2 Obinrin náà lóyún, ó sì bí ọmọkunrin kan. Nígbà tí ó rí i pé ọmọ náà jẹ́ arẹwà, ó gbé e pamọ́ fún oṣù mẹta.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 2

Wo Ẹkisodu 2:2 ni o tọ