7 Ẹ̀gbọ́n ọmọ náà bá bi ọmọbinrin Farao pé, “Ṣé kí n lọ pe olùtọ́jú kan wá lára àwọn obinrin Heberu, kí ó máa bá ọ tọ́jú ọmọ yìí?”
Ka pipe ipin Ẹkisodu 2
Wo Ẹkisodu 2:7 ni o tọ