Ẹkisodu 20:21 BM

21 Àwọn eniyan náà dúró lókèèrè, bí Mose tí ń súnmọ́ òkùnkùn biribiri tí ó ṣú bo ibi tí Ọlọrun wà.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 20

Wo Ẹkisodu 20:21 ni o tọ