Ẹkisodu 20:25 BM

25 Bí ẹ bá fi òkúta tẹ́ pẹpẹ fún mi, ẹ má lo òkúta tí wọ́n bá gbẹ́, nítorí pé bí ẹ bá fi ohun èlò yín ṣiṣẹ́ lára òkúta náà, ẹ ti sọ ọ́ di aláìmọ́.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 20

Wo Ẹkisodu 20:25 ni o tọ