Ẹkisodu 20:4 BM

4 “O kò gbọdọ̀ yá èrekére fún ara rẹ, kì báà ṣe àwòrán ohun tí ó wà ní òkè ọ̀run, tabi ti ohun tí ó wà ní orí ilẹ̀, tabi ti ohun tí ó wà ninu omi ní abẹ́ ilẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 20

Wo Ẹkisodu 20:4 ni o tọ