Ẹkisodu 21:13 BM

13 Ṣugbọn bí olúwarẹ̀ kò bá mọ̀ọ́nmọ̀ pa á, tí ó jẹ́ pé ó ṣèèṣì ni, irú ẹni bẹ́ẹ̀ lè sálọ sí ibìkan tí n óo yàn fún yín.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 21

Wo Ẹkisodu 21:13 ni o tọ