Ẹkisodu 21:16 BM

16 “Ẹnikẹ́ni tí ó bá jí eniyan gbé, kì báà jẹ́ pé ó ti tà á, tabi kí wọ́n ká a mọ́ ọn lọ́wọ́, pípa ni kí wọ́n pa á.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 21

Wo Ẹkisodu 21:16 ni o tọ