Ẹkisodu 21:2 BM

2 Bí ẹnikẹ́ni bá ra Heberu kan lẹ́rú, ọdún mẹfa ni ẹrú náà óo fi sìn ín, ní ọdún keje, ó níláti dá a sílẹ̀ lọ́fẹ̀ẹ́ láìgba ohunkohun lọ́wọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 21

Wo Ẹkisodu 21:2 ni o tọ