20 “Bí ẹnìkan bá lu ẹrukunrin tabi ẹrubinrin rẹ̀ ní kùmọ̀, tí ẹrú náà bá kú mọ́ ọn lọ́wọ́, olúwarẹ̀ yóo jìyà.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 21
Wo Ẹkisodu 21:20 ni o tọ