Ẹkisodu 21:4 BM

4 Bí olówó rẹ̀ bá fẹ́ aya fún un, tí aya náà sì bímọ fún un, lọkunrin ati lobinrin, olówó rẹ̀ ni ó ni aya ati àwọn ọmọ patapata, òun nìkan ni òfin dá sílẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 21

Wo Ẹkisodu 21:4 ni o tọ