Ẹkisodu 22:13 BM

13 Bí ó bá jẹ́ pé ẹranko burúkú ni ó pa á, bí ó bá ní ohun tí ó lè fi ṣe ẹ̀rí, tí ó sì fi ohun náà han ẹni tí ó ni ẹran náà, kò ní san ẹ̀san ẹran náà pada.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 22

Wo Ẹkisodu 22:13 ni o tọ