17 Bí baba wundia náà bá kọ̀ jálẹ̀ pé òun kò ní fi ọmọ òun fún un, yóo san iye owó tí wọ́n bá ń san ní owó orí wundia tí kò mọ ọkunrin.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 22
Wo Ẹkisodu 22:17 ni o tọ