Ẹkisodu 23:2 BM

2 O kò gbọdọ̀ bá ọ̀pọ̀ eniyan kẹ́gbẹ́ láti ṣe ibi, tabi kí o tẹ̀lé ọ̀pọ̀ eniyan láti jẹ́rìí èké tí ó lè yí ìdájọ́ po.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 23

Wo Ẹkisodu 23:2 ni o tọ