Ẹkisodu 23:20 BM

20 “Wò ó, mo rán angẹli kan ṣiwaju rẹ láti pa ọ́ mọ́ ní ọ̀nà rẹ, ati láti mú ọ wá sí ibi tí mo ti tọ́jú fún ọ.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 23

Wo Ẹkisodu 23:20 ni o tọ