Ẹkisodu 24:11 BM

11 Ọlọrun kò sì pa àwọn àgbààgbà Israẹli náà lára rárá, wọ́n rí Ọlọrun, wọ́n jẹ, wọ́n sì mu.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 24

Wo Ẹkisodu 24:11 ni o tọ