17 Lójú àwọn eniyan Israẹli, ìrísí ògo OLUWA lórí òkè náà dàbí iná ńlá tí ń jóni ní àjórun.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 24
Wo Ẹkisodu 24:17 ni o tọ