Ẹkisodu 25:16 BM

16 Kí o fi àkọsílẹ̀ majẹmu ẹ̀rí tí n óo gbé lé ọ lọ́wọ́ sinu àpótí náà.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 25

Wo Ẹkisodu 25:16 ni o tọ